Thursday, 10 January 2013
YORÙBÁ 302: YORÙBÁ LEXICAL CATEGORIES
YORÙBÁ 302: YORÙBÁ LEXICAL CATEGORIES
(ÌSỌ̀RÍ Ọ̀RỌ̀ LÉDÈ YORÙBÁ)
Olùkọ́: Ọ̀mọ̀wé Ọládiípọ̀ Ajíbóyè
Àkókò ìdánilẹ́kọ̀ọ́: Ọjọ́ Àkókò Yàrá ìkẹ́kọ̀ọ́
Ọjọ́’rú 9am-10am RM 305
Ọjọ́’bọ: 8am-9am RM 208
Àdírẹ́sì Ọọ́fíìsì: RM A512
Nọ́ńbà ìbánisọ̀rọ̀: 0805-174-0201, 08126932123
email oladiipo@yahoo.com
Àkókò tí ẹ lè rí mi: Ọjọ́’rú 4-5pm
Ohun tí a ń retí láti ọ̀dọ̀ akẹ́kọ̀ọ́ nínú ẹ̀kọ́ yìí:
Wíwá sí ìdánilẹ́kọ̀ọ́ déédé àti kíkópa 05%
Iṣẹ́ àṣetiléwá 15%
Ìdánwò ráńpẹ́ 20%
Ìdánwaò àṣekágbá 60%
ÀPÈJÚWE IṢẸ́:
Ohun tí is̟é̟ yìí dálé ni ìsọ̀rí ọ̀rọ̀ lédè Yorùbá. A ó ṣe àgbéyè̟wò oríṣiríṣi òṣùwọ̀n fún pípín ò̟rò̟ Yorùbá sí ìsò̟rí: àmúye̟ àti àlébù òs̟ùwò̟n kò̟ò̟kan. Ohun mìíràn tí is̟é̟ yìí máa dálé ni àyè̟wò kíkún nípà ìsò̟rí ò̟rò̟-orúko̟, ò̟rò̟-aró̟pò orúko̟, ò̟rò̟-ìs̟e, ò̟rò̟-àpèjúwe, ọ̀rọ̀-àpọ́nlé àti ọ̀rọ̀-atoọ́kùn. A ó sì wá ṣe àríwísí lórí ìkógojá àwọn ìsọ̀rí wọ̀nyí gẹ́gẹ́ bí ojúlówó ìsọ̀rí-ọ̀rọ̀ lédè náà.
Àkóónú iṣẹ́
Ìfáárà sí ẹ̀kọ́ yìí:
Oṣùwọ̀n ìpín ọ̀rọ̀ sí ìsọ̀rí
Ìlò/Iṣẹ́ tí ọ̀rọ̀ ń ṣe
Ìtumọ̀ tí ọ̀rọ̀ ní
Ìhun
Ọ̀rọ̀-orúkọ
Ọ̀rọ̀-ìṣe
Ọ̀rọ̀-àpèjúwe
Ọ̀rọ̀-àpọ́nle
Ọ̀rọ̀-atọ́kùn
Ìgbéléwọ̀n ìsọ̀rí kọ̀ọ̀kan pẹ̀lú ẹ̀rí láti inú èdè Yorùbá
Subscribe to:
Posts (Atom)