Thursday, 10 January 2013

YORÙBÁ 302: YORÙBÁ LEXICAL CATEGORIES

YORÙBÁ 302: YORÙBÁ LEXICAL CATEGORIES (ÌSỌ̀RÍ Ọ̀RỌ̀ LÉDÈ YORÙBÁ) Olùkọ́: Ọ̀mọ̀wé Ọládiípọ̀ Ajíbóyè Àkókò ìdánilẹ́kọ̀ọ́: Ọjọ́ Àkókò Yàrá ìkẹ́kọ̀ọ́ Ọjọ́’rú 9am-10am RM 305 Ọjọ́’bọ: 8am-9am RM 208 Àdírẹ́sì Ọọ́fíìsì: RM A512 Nọ́ńbà ìbánisọ̀rọ̀: 0805-174-0201, 08126932123 email oladiipo@yahoo.com Àkókò tí ẹ lè rí mi: Ọjọ́’rú 4-5pm Ohun tí a ń retí láti ọ̀dọ̀ akẹ́kọ̀ọ́ nínú ẹ̀kọ́ yìí: Wíwá sí ìdánilẹ́kọ̀ọ́ déédé àti kíkópa 05% Iṣẹ́ àṣetiléwá 15% Ìdánwò ráńpẹ́ 20% Ìdánwaò àṣekágbá 60% ÀPÈJÚWE IṢẸ́: Ohun tí is̟é̟ yìí dálé ni ìsọ̀rí ọ̀rọ̀ lédè Yorùbá. A ó ṣe àgbéyè̟wò oríṣiríṣi òṣùwọ̀n fún pípín ò̟rò̟ Yorùbá sí ìsò̟rí: àmúye̟ àti àlébù òs̟ùwò̟n kò̟ò̟kan. Ohun mìíràn tí is̟é̟ yìí máa dálé ni àyè̟wò kíkún nípà ìsò̟rí ò̟rò̟-orúko̟, ò̟rò̟-aró̟pò orúko̟, ò̟rò̟-ìs̟e, ò̟rò̟-àpèjúwe, ọ̀rọ̀-àpọ́nlé àti ọ̀rọ̀-atoọ́kùn. A ó sì wá ṣe àríwísí lórí ìkógojá àwọn ìsọ̀rí wọ̀nyí gẹ́gẹ́ bí ojúlówó ìsọ̀rí-ọ̀rọ̀ lédè náà. Àkóónú iṣẹ́ Ìfáárà sí ẹ̀kọ́ yìí: Oṣùwọ̀n ìpín ọ̀rọ̀ sí ìsọ̀rí Ìlò/Iṣẹ́ tí ọ̀rọ̀ ń ṣe Ìtumọ̀ tí ọ̀rọ̀ ní Ìhun Ọ̀rọ̀-orúkọ Ọ̀rọ̀-ìṣe Ọ̀rọ̀-àpèjúwe Ọ̀rọ̀-àpọ́nle Ọ̀rọ̀-atọ́kùn Ìgbéléwọ̀n ìsọ̀rí kọ̀ọ̀kan pẹ̀lú ẹ̀rí láti inú èdè Yorùbá

No comments:

Post a Comment